Kini o n ri?
ninu arin, ẹnikan joko pẹlu ẹsẹ mẹta, ni ẹgbẹ, eniyan meji n ṣiṣẹ lori nkan kan, e.g. ikọwe/ìkà.
ọkùnrin kan tó ní afro tí ń wọ ibèèrè.
awọn ọmọbirin n jo
obinrin to binu
shiva ni aarin pẹlu awọn jagunjagun ni ẹgbẹ mejeeji.
sheep
dancers
obinrin kan ti o ni irun ori duro ni aarin pẹlu eniyan meji ti n tẹ́ ẹ̀dá wọn ni ẹgbẹ́ mejeji.
obinrin ibile afirika